YORUBA NATION ANTHEM
(Download word document or pdf, check the files below the texts)
- Iṣẹ wa fun’le wa
Fún ilẹ ibi wa
Ka gbega (2X)
Ka gbega f’ayé rí
2. Igbagbọ wa ni pe
B’a ti b’ẹrú
La b’ọmọ
K’a ṣiṣẹ (3X)
K’a jọla
3. Iṣọkan
At’ominira
Ni K’ejẹ
K’ama lepa
Itẹsiwaju
F’opo ire
A t’oun
To dara
4. Omo Oodua dide
Bosi ipo etọ rẹ
Iwọ ni
Imọlẹ
Gbogbo adulawọ
————————————————————
Webiste: www.adeola.blog
Twitter @aderinola
Instagram: oduduwarepublik
Facebook. www.facebook.com/adeola
Hashtags: #YorubaNation #YorubaNationNow
Download pdf or word